Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  September 2017

September 25–​October 1

DÁNÍẸ́LÌ 4-6

September 25–​October 1
 • Orin 67 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ṣé Ò Ń Sin Jèhófà Láìyẹsẹ̀?”: (10 min.)

  • Da 6:7-10​—Dáníẹ́lì fi ẹ̀mí ara rẹ̀ wewu kó lè máa sin Jèhófà láìyẹsẹ̀ (w10 11/15 6 ¶16; w06 11/1 24 ¶12)

  • Da 6:16, 20​—Ọba Dáríúsì rí i pé Dáníẹ́lì ní àjọṣe tímọ́tímọ́ pẹ̀lú Jèhófà (w03 9/15 15 ¶2)

  • Da 6:22, 23​—Jèhófà bù kún Dáníẹ́lì torí pé ó ń sìn ín láìyẹsẹ̀ (w10 2/15 18 ¶15)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Da 4:10, 11, 20-22​—Kí ni arabaríbí igi inú àlá Nebukadinésárì dúró fún? (w07 9/1 18 ¶5)

  • Da 5:17, 29​—Kí nìdí tí Dáníẹ́lì kò fi kọ́kọ́ gba ẹ̀bùn tí Ọba Bẹliṣásárì fún un, àmọ́ tó wá gbà á nígbà tó yá? (w88 10/1 30 ¶3-5; dp 109 ¶22)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Da 4:29-37

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) inv

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) inv​—Nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà, o ti fún un ní ìwé ìkésíni sí àwọn ìpàdé. Ṣe ìpadàbẹ̀wò.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 120 ¶16​—Fún akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní ìṣírí pé kó jẹ́ adúróṣinṣin kódà tí àwọn ará ilé rẹ̀ bá ń ṣe inúnibíni sí i.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI