Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  September 2017

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | DÁNÍẸ́LÌ 1-3

Jèhófà Máa San Wá Lẹ́san Tá A Bá Jẹ́ Adúróṣinṣin sí I

Jèhófà Máa San Wá Lẹ́san Tá A Bá Jẹ́ Adúróṣinṣin sí I

Ìtàn àwọn Hébérù mẹ́ta yẹn ń fún wa níṣìírí láti jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà

3:16-20, 26-29

Kí ni àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí fi hàn pé a gbọ́dọ̀ máa ṣe tá a bá fẹ́ jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà?