Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  September 2017

 MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Jẹ́ Adúróṣinṣin Nígbà Ìdẹwò

Jẹ́ Adúróṣinṣin Nígbà Ìdẹwò

Wo fídíò náà, Jẹ́ Adúróṣinṣin Bíi Jésù​—Nígbà Ìdẹwò, lẹ́yìn náà, dáhùn àwọn ìbéèrè yìí:

  • Ìdẹwò wo ni Ṣẹ́gun dojú kọ tó lè mú kó jẹ́ aláìdúróṣinṣin?

  • Kí ló ran Sẹ́gun lọ́wọ́ tó fi jẹ́ adúróṣinṣin?

  • Báwo ni ìdúróṣinṣin rẹ̀ ṣe fi ìyìn fún Jèhófà?