• Orin 131 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Jèhófà Máa San Wá Lẹ́san Tá A Bá Jẹ́ Adúróṣinṣin sí I”: (10 min.)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Da 1:5, 8​—Kí nìdí tí Dáníẹ́lì àtàwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta fi gbà pé táwọn bá jẹ oúnjẹ tí ọba gbé kalẹ̀, ó máa sọ àwọn di ẹlẹ́gbin? (it-2 382)

  • Da 2:44​—Kí nìdí tí Ìjọba Ọlọ́run fi máa fòpin sí àwọn ìjọba ayé tí ère yẹn ṣàpẹẹrẹ? (w12 6/15 17, àpótí; w01 10/15 6 ¶4)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Da 2:31-43

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 40:22​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ro 15:4​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni​—Fún un ní káàdì ìkànnì JW.ORG.

 • Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w17.02 29-30​—Àkòrí: Ṣé Jèhófà Ti Kọ́kọ́ Máa Ń Díwọ̀n Ohun Tá A Lè Mú Mọ́ra Kó Tó Wá Pinnu Irú Àdánwò Tó Máa Jẹ́ Kó Dé Bá Wa?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI