Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  September 2016

September 5 sí 11

SÁÀMÙ 119

September 5 sí 11
 • Orin 48 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Máa Rìn Nínú Òfin Jèhófà”: (10 min.)

  • Sm 119:1-8—Tá a bá fẹ́ ní ojúlówó ayọ̀, a gbọ́dọ̀ máa rìn nínú òfin Ọlọ́run (w05 4/15 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 3 àti 4)

  • Sm 119:33-40—Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run máa ń fún wa ní ìgboyà láti fara da àwọn ìṣòro (w05 4/15 ojú ìwé 12 ìpínrọ̀ 12)

  • Sm 119:41-48—Tá a bá ní ìmọ̀ tó péye nípa Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, èyí á jẹ́ ká máa fi ìgboyà wàásù (w05 4/15 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 13 àti 14)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Sm 119:71—Àǹfààní wo la lè rí nínú ìpọ́njú? (w06 9/1 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 4)

  • Sm 119:96—Kí ni ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ náà “èmi ti rí òpin gbogbo ìjẹ́pípé”? (w06 9/1 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 5)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 119:73-93

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n kọ àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ wọn sílẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI