Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  October 2017

October 9-​15

DÁNÍẸ́LÌ 10-12

October 9-​15
 • Orin 31 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Jèhófà Mọ Ohun Tó Máa Ṣẹlẹ̀ sí Àwọn Ọba”: (10 min.)

  • Da 11:2​—Àwọn ọba mẹ́rin díde ní Ilẹ̀ Ọba Páṣíà (dp 212-213 ¶5-6)

  • Da 11:3​—Alẹkisáńdà Ńlá dé (dp 213 ¶8)

  • Da 11:4​—Ìjọba Alẹkisáńdà pín sí apá mẹ́rin (dp 214 ¶11)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Da 12:3​—Àwọn wo ni “àwọn tí ó ní ìjìnlẹ̀ òye,” ìgbà wo ni wọ́n sì “máa tàn bí ìtànyòò òfuurufú”? (w13 7/15 13 ¶16, àfikún àlàyé)

  • Da 12:13​—Báwo ni Dáníẹ́lì ṣe máa “dìde”? (dp 315 ¶18)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Da 11:​28-39

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.5 ​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.5 ​—Nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà, o ti fún un ní ìwé ìròyìn yìí. Máa bá ìjíròrò náà lọ kí o sì jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w16.11 5-6 ¶7-8​—Àkòrí: Báwo La Ṣe Lè Máa Fúnni Níṣìírí Bíi Ti Jèhófà?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI