Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  October 2017

October 30–​November 5

JÓẸ́LÌ 1-3

October 30–​November 5
 • Orin 143 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Àwọn Ọmọkùnrin Yín àti Àwọn Ọmọbìnrin Yín Yóò Máa Sọ Tẹ́lẹ̀’: (10 min.)

  • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jóẹ́lì.]

  • Joe 2:​28, 29​—Àwọn Kristẹni ẹni àmì òróró jẹ́ agbọ̀rọ̀sọ fún Jèhófà (w02 8/1 15 ¶4-5; jd 167 ¶4)

  • Joe 2:​30-32​—Àwọn tó bá ń ké pe orúkọ Jèhófà nìkan ló máa rí ìgbàlà ní ọjọ́ amúnikún-fún-ẹ̀rù rẹ̀ (w07 10/1 13 ¶2)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Joe 2:​12, 13​—Kí ni àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí kọ́ wa nípa ojúlówó ìrònúpìwàdà? (w07 10/1 13 ¶5)

  • Joe 3:14​—Kí ni “pẹ̀tẹ́lẹ̀ rírẹlẹ̀ ti ìpinnu”? (w07 10/1 13 ¶3)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Joe 2:28–3:8

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Káàdì ìkànnì JW.ORG

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Káàdì ìkànnì JW.ORG​—Nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà, o ti fún un ní káàdì yìí. Máa bá ìjíròrò náà lọ, kí o sì fi fídíò kan hàn án láti orí ìkànnì jw.org.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 196-197 ¶3-5

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI