14:2, 4, 9

Inú Jèhófà máa dùn tó o bá fún un ní ohun tó dára jù lọ, ó sì máa ṣe ìwọ náà láǹfààní

ÀJỌṢE RẸ PẸ̀LÚ JÈHÓFÀ

  1. O rú ẹbọ ìyìn sí Jèhófà

  2. Jèhófà dárí jì ẹ́, ó tẹ́wọ́ gbà ẹ́, o sì di ọ̀rẹ́ rẹ̀

  3. Wàá rí àǹfààní tó wà nínú kéèyàn máa ṣègbọràn sí àwọn àṣẹ Jèhófà, èyí á sì jẹ́ kó máa wù ẹ́ láti túbọ̀ máa yìn ín

Àwọn ọ̀nà wo ni mo lè gbà fún Jèhófà ní ohun tó dára jù?