Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

October 23-​29

HÓSÉÀ 8-14

October 23-​29
 • Orin 153 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Fún Jèhófà Ní Ohun Tó Dára Jù Lọ”: (10 min.)

  • Ho 14:2​—Jèhófà mọyì bá a ṣe ń fi ẹnu wa yìn ín (w07 4/1 20 ¶2)

  • Ho 14:4​—Jèhófà máa ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ ji àwọn tó ń mú irú ẹbọ ìyìn bẹ́ẹ̀ wá, ó máa ń tẹ́wọ́ gbà wọ́n, ó sì máa ń bá wọn dọ́rẹ̀ẹ́ (w11 2/15 16 ¶15)

  • Ho 14:9​—Àǹfààní wà nínú ká máa tẹ̀ lé àwọn ìlànà Jèhófà (jd 87 ¶11)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Ho 10:12​—Kí la lè ṣe láti jọlá ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀? (w05 11/15 28 ¶7)

  • Ho 11:1​—Báwo ni ọ̀rọ̀ yìí ṣe ṣẹ sí Jésù lára? (w11 8/15 10 ¶10)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ho 8:​1-14

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-35

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-35​—Nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà, o ti fún un ní ìwé àṣàrò kúkúrú yìí. Máa bá ìjíròrò náà lọ, kí o sì ṣàlàyé kókó kan tí onílé sọ pé òun ò fara mọ́.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 152 ¶13-15​—⁠Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI