Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  October 2017

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | DÁNÍẸ́LÌ 7-9

Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì Sọ Ìgbà Tí Mèsáyà Máa Dé

Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì Sọ Ìgbà Tí Mèsáyà Máa Dé
WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

9:24-27

“ÀÁDỌ́RIN Ọ̀SẸ̀” (490 ỌDÚN)

 • “Ọ̀SẸ̀ MÉJE” (49 ỌDÚN)

  455 B.C.E. “Ọ̀rọ̀ náà láti mú Jerúsálẹ́mù padà bọ̀ sípò”

  406 B.C.E. Wọ́n tún Jerúsálẹ́mù kọ́

 • “Ọ̀SẸ̀ MÉJÌ-LÉ-LỌ́GỌ́TA” (434 ỌDÚN)

 • “Ọ̀SẸ̀ KAN” (7 ỌDÚN)

  29 C.E. Mèsáyà dé

  33 C.E. Wọ́n “ké” Mèsáyà kúrò

  36 C.E. Òpin “àádọ́rin ọ̀sẹ̀”