Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

October 2-​8

DÁNÍẸ́LÌ 7-9

October 2-​8
 • Orin 116 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì Sọ Ìgbà Tí Mèsáyà Máa Dé”: (10 min.)

  • Da 9:24​—Ikú ìrúbọ tí Mèsáyà kú ló mú kí Ọlọ́run lè máa dárí ẹ̀ṣẹ̀ jì wá (it-2 902 ¶2)

  • Da 9:25​—Mèsáyà náà dé ní òpin ọ̀sẹ̀ mọ́kàndínláàádọ́rin [69] ti ọdún (it-2 900 ¶7)

  • Da 9:​26, 27a​—Wọ́n pa Mèsáyà náà ní àárín àádọ́rin ọ̀sẹ̀ [70] ti ọdún (it-2 901 ¶2, 5)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Da 9:24​—Ìgbà wo ni a fòróró yan “Ibi Mímọ́ nínú Àwọn Ibi Mímọ́”? (w01 5/15 27)

  • Da 9:27​—Májẹ̀mú wo ló ń ṣiṣẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ títí di òpin àádọ́rin ọ̀sẹ̀ ti ọdún, tàbí ọdún 36 Sànmánì Kristẹni? (w07 9/1 20 ¶4)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Da 7:1-10

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò tó dá lórí “Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò.” Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Gba àwọn ará níyànjú kí wọ́n tètè pa dà lọ sọ́dọ̀ àwọn tó fìfẹ́ hàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI