Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  October 2017

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | HÓSÉÀ 1-7

Ṣé Inú Rẹ Máa Ń Dùn sí Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Bíi Ti Jèhófà?

Ṣé Inú Rẹ Máa Ń Dùn sí Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Bíi Ti Jèhófà?

Ẹni tó bá ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ jẹ́ olóòótọ́, ẹni tó ṣeé fọkàn tán, àdúrótini àti adúróṣinṣin. Jèhófà fi ọ̀rọ̀ Hóséà àti Gómérì ìyàwó rẹ̀ tó jẹ́ aláìṣòótọ́ kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti ìdáríjì.​—Ho 1:2; 2:7; 3:​1-5.

Báwo ni Gómérì ṣe fi hàn pé òun kò ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀?

Báwo ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe fi hàn pé wọn kò ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀?

Báwo ni Hóséà ṣe fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn?

Báwo ni Jèhófà ṣe fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn?

RONÚ LÓRÍ ÌBÉÈRÈ YÌÍ: Báwo ni mo ṣe lè fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí Jèhófà?