• Orin 18 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ṣé Inú Rẹ Máa Ń Dùn sí Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Bíi Ti Jèhófà?”: (10 min.)

  • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Hóséà.]

  • Ho 6:​4, 5​—Inú Jèhófà kò dùn sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì torí pé wọn ò ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ (w10 8/15 25 ¶18)

  • Ho 6:6​—Inú Jèhófà máa ń dùn sí wa tá a bá ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ (w07 9/15 16 ¶8; w07 6/15 27 ¶7)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Ho 1:7​—Ìgbà wo ni Jèhófà fi àánú hàn sí ilé Júdà tó sì gbà wọ́n là? (w07 9/15 14 ¶7)

  • Ho 2:18​—Báwo ni ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe ṣẹ nígbà àtijọ́, báwo ló sì ṣe máa ṣẹ lọ́jọ́ iwájú? (w05 11/15 20 ¶16; g05-E 9/8 12 ¶2)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ho 7:​1-16

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Jo 5:3​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni​—Pe ẹni náà wá sí àwọn ìpàdé wa.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Di 30:​11-14; Ais 48:​17, 18​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni​—Sọ fún ẹni náà nípa ìkànnì jw.org. (Wo mwb16.08 8 ¶2.)

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 12-13 ¶16-18 ​—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI