Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  October 2016

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÒWE 17-21

Máa Wà Ní Àlàáfíà Pẹ̀lú Àwọn Ẹlòmí ì

Máa Wà Ní Àlàáfíà Pẹ̀lú Àwọn Ẹlòmí ì

Àlááfíà tó wà láàárín àwa èèyàn Jèhófà kì í ṣe èèṣì. Tí èdèkòyédè bá ṣẹlẹ̀, ó lè múnú bí wa gan-an, àmọ́ ìmọ̀ràn inú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run máa ń pẹ̀tù sí wa lọ́kàn.

Tí àìgbọ́ra-ẹni-yé bá ṣẹlẹ̀, àwọn Kristẹni olóòótọ́ máa ń wá àlááfíà nípa . . .

19:11

  • ṣíṣàì-fara-ya

18:13, 17

  • rírí i pé àwọn mọ gbogbo bọ́rọ̀ ṣe jẹ́ kí wọ́n tó fèsì

17:9

  • jíjẹ́ kí ìfẹ́ mú kí wọ́n dárí ji ẹni tó ṣẹ̀ wọ́n