Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  October 2016

October 17 sí 23

Òwe 12-16

October 17 sí 23
 • Orin 69 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ọgbọ́n Dára Ju Wúrà Lọ”: (10 min.)

  • Owe 16:16, 17—Ọlọ́gbọ́n èèyàn máa ń kẹ́kọ̀ọ́ ó sì máa ń fi Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sílò (w07 7/15 ojú ìwé 8)

  • Owe 16:18, 19—Ọlọ́gbọ́n èèyàn kì í gbéra ga tàbí jọ ara rẹ̀ lójú (w07 7/15 ojú ìwé 8 àti 9)

  • Owe 16:20-24—Ọlọ́gbọ́n èèyàn máa ń sọ̀rọ̀ rere tó lè ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ (w07 7/15 ojú ìwé 9 àti 10)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Owe 15:15—Báwo la ṣe lè túbọ̀ láyọ̀ nígbèésí ayé? (01/14 ojú ìwé 16)

  • Owe 16:4—Ọ̀nà wo ni Jèhófà gbà mú kí àwọn ẹni búburú ṣiṣẹ́ “fún ète rẹ̀”? (w07 5/15 ojú ìwé 18 àti 19)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Owe 15:18–16:6

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jo 11:11-14—Máa fi òtítọ́ kọ́ni. Pe ẹni náà wá sí ìpàdé òpin ọ̀sẹ̀.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 3:1-6; Ro 5:12—Máa fi òtítọ́ kọ́ni. Pe ẹni náà wá sí ìpàdé òpin ọ̀sẹ̀.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 191 ìpínrọ̀ 18 àti 19—Pe akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì náà wá sí ìpàdé.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI