Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  November 2017

November 27–​December 3

NÁHÚMÙ 1–HÁBÁKÚKÙ 3

November 27–​December 3
 • Orin 154 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Wà Lójúfò Kó O sì Máa Sin Jèhófà Nìṣó”: (10 min.)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Na 1:8; 2:6​—Báwo ni wọ́n ṣe pa ìlú Nínéfè run? (w07 11/15 9 ¶2)

  • Hab 3:​17-19​—Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ṣeé ṣe kí nǹkan nira fún wa ṣáájú Amágẹ́dọ́nì àti nígbà tó bá ń lọ lọ́wọ́, kí ló dá wa lójú? (w07 11/15 10 ¶10)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Hab 2:15–3:6

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI