Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  November 2017

November 20-​26

MÍKÀ 1-7

November 20-​26
 • Orin 26 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Kí Ni Jèhófà Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa?”: (10 min.)

  • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Míkà.]

  • Mik 6:​6, 7​—Tí a kò bá hùwà tó dáa sí àwọn èèyàn, Jèhófà kò ní tẹ́wọ́ gba àwọn ẹbọ wa (w08 5/15 6 ¶20)

  • Mik 6:8​—Àwọn ohun tí Jèhófà ń béèrè lọ́wọ́ wa kò ju agbára wa lọ (w12 11/1 22 ¶4-7)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Mik 2:12​—Báwo ni àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣe ṣẹ? (w07 11/1 15 ¶6)

  • Mik 7:7​—Kí nìdí tó fi yẹ ká “fi ẹ̀mí ìdúródeni hàn” sí Jèhófà? (w03 8/15 24 ¶20)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mik 4:​1-10

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 83:18​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 3:14​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 123-124 ¶20-21.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI