Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

November 21 sí 27

ONÍWÀÁSÙ 7-12

November 21 sí 27
  • Orin 41 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 2Ti 3:1-5 —Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 44:27–45:2 —Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 25 àti 26 ìpínrọ̀ 18 sí 20—Pe akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì náà wá sí ìpàdé.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI