Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

 MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Jèhófà Á Jẹ́ Kó O Nígboyà

Jèhófà Á Jẹ́ Kó O Nígboyà

Tó o bá ṣì wà ní iléèwé, ṣé ẹ̀rù máa ń bà ẹ́ láti jẹ́ káwọn èèyàn mọ̀ pé Ẹlẹ́rìí Jèhófà ni ẹ́, tó sì máa ń ṣòro fún ẹ láti wàásù? Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, báwo lo ṣe lè “máyàle” kó o lè máa fi ìgboyà sọ̀rọ̀ Ọlọ́run? (1Tẹ 2:2) Kí nìdí tó fi yẹ kó o ṣe bẹ́ẹ̀? Wo fídíò náà Jèhófà Á Jẹ́ Kó O Nígboyà, lẹ́yìn náà, kó o wá dáhùn àwọn ìbéèrè yìí:

  1. Àpẹẹrẹ wo nínú Bíbélì ló mú kí Tósìn nígboyà?

  2. Báwo ni ìdánrawò ṣe ran Tósìn lọ́wọ́?

  3. Kí nìdí tó fi yẹ kó o máa wàásù fáwọn ọmọ iléèwé rẹ?

  4. Ẹ̀kọ́ wo làwọn tó ti kúrò níléèwé lè rí kọ́ látinú fídíò yìí?