Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  May 2017

May 22-​28

Jeremáyà 44-48

May 22-​28
 • Orin 70 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Má Ṣe ‘Wá Àwọn Ohun Ńláńlá fún Ara Rẹ’”: (10 min.)

  • Jer 45:2, 3​—Èrò òdì tó gba Bárúkù lọ́kàn kó wàhálà bá a (jr 104-105 ¶4-6)

  • Jer 45:4, 5a​—Jèhófà fìfẹ́ tọ́ Bárúkù sọ́nà (jr 103 ¶2)

  • Jer 45:5b​—Ọlọ́run dá ẹ̀mí Bárúkù sí torí pé ó gbájú mọ́ àwọn ohun tó ṣe pàtàkì jù (w16.07 8 ¶6)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Jer 48:13​—Kí nìdí tí ojú á fi ti àwọn ọmọ Móábù nítorí Kémóṣì? (it-1 430)

  • Jer 48:42​—Kí nìdí tí àsọtẹ́lẹ̀ Jèhófà pé ìlú Móábù máa pa run fi mú kí ìgbàgbọ́ wa túbọ̀ lágbára? (it-2 422 ¶2)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 47:1-7

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) hf​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) hf​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 199 ¶9-10​—Ní ṣókí, kọ́ akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì rẹ bó ṣe lè ṣe ìwádìí nípa ìṣòro kan tó ní.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI