Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 35-38

Ebedi-mélékì Jẹ́ Onígboyà àti Onínúure

Ebedi-mélékì Jẹ́ Onígboyà àti Onínúure

Ebedi-mélékì jẹ́ ìjòyè láàfin Ọba Sedekáyà, èèyàn dáadáa sì ni

38:7-13

  • Ó lo ìgboyà, ó sì gbé ìgbésẹ̀ lójú ẹsẹ̀ láti lọ bá Ọba Sedekáyà kó lè yọ Jeremáyà jáde nínú kòtò ẹlẹ́rẹ̀

  • Ó fi àwọn àgékù aṣọ àti aṣọ fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ sí abíyá Jeremáyà kí okùn tí wọ́n fi ń fà á sókè má bàa ṣe é léṣe; èyí fi hàn pé ó jẹ́ onínúure