Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  May 2017

 MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Jèhófà Kì Í Gbàgbé Ìfẹ́ Tá A Fi Hàn

Jèhófà Kì Í Gbàgbé Ìfẹ́ Tá A Fi Hàn

WO FÍDÍÒ NÁÀ, JÈHÓFÀ KÌ Í GBÀGBÉ ÌFẸ́ TÁ A FI HÀN, KÓ O SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Ìṣòro wo làwọn àgbàlagbà máa ń ní?

  • Ìwà rere wo làwọn àgbàlagbà máa ń ní?

  • Ẹ̀yin àgbàlagbà, ìṣírí wo lẹ rí nínú Léfítíkù 19:32 àti Òwe 16:31?

  • Ojú wo ni Jèhófà fi ń wo àwọn ìrànṣẹ́ rẹ̀ tó ti dàgbà, àmọ́ tí wọn ò lè ṣe tó ti tẹ́lẹ̀ mọ́ lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ wọn?

  • Kí ni Jèhófà fẹ́ ká máa ṣe, kódà bá a bá tiẹ̀ ti dàgbà?

  • Báwo làwọn àgbàlagbà ṣe lè fún àwọn ọ̀dọ́ níṣìírí?

  • Báwo ni arákùnrin tàbí arábìnrin àgbàlagbà kan ṣe fún ẹ níṣìírí lẹ́nu àìpẹ́ yìí?