Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  May 2017

May 15-​21

Jeremáyà 39-43

May 15-​21
 • Orin 133 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Jèhófà Máa San Olúkúlùkù Lẹ́san Níbàámu Pẹ̀lú Iṣẹ́ Rẹ̀”: (10 min.)

  • Jer 39:4-7​—Sedekáyà jìyà nítorí pé ó ṣàìgbọ́ràn sí Jèhófà (it-2 1228 ¶4)

  • Jer 39:15-18​—Jèhófà fi hàn pé òun mọyì bí Ebedi-mélékì ṣe gbẹ́kẹ̀ lé òun (w12 5/1 31 ¶5)

  • Jer 40:1-6​—Jèhófà tọ́jú Jeremáyà ìránṣẹ́ rẹ̀ olóòótọ́ (it-2 482)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Jer 42:1-3; 43:2, 4​—Kí la rí kọ́ látinú àṣìṣe Jóhánánì? (w03 5/1 10 ¶10)

  • Jer 43:6, 7​—Báwo ni ìṣẹ̀lẹ̀ tí àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀ ṣe ṣe pàtàkì tó? (it-1 463 ¶4)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 40:11–41:3

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 46:10​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣi 12:7-9, 12​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 153 ¶19-20​—Pe ẹni náà wá sí ìpàdé.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI