Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  May 2017

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 32-34

Àmì Tó Fi Hàn Pé Jèhófà Máa Mú Ísírẹ́lì Padà Bọ̀ Sípò

Àmì Tó Fi Hàn Pé Jèhófà Máa Mú Ísírẹ́lì Padà Bọ̀ Sípò
WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

32:9-14

  • Jeremáyà ṣe àwọn ohun tó yẹ nígbà tó fẹ́ ra pápá.

33:​10, 11

  • Jèhófà ṣèlérí fún àwọn tó wà nígbèkùn pé tí wọ́n bá gba ìbáwí, òun máa dárí jì wọ́n, wọ́n á sì pa dà sí Ísírẹ́lì; ìyẹn fi hàn pé ẹni rere ni Jèhófà.

Àwọn ohun rere wo ni Jèhófà ti ṣe fún ẹ?