Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  May 2017

May 1-​7

JEREMÁYÀ 32-34

May 1-​7
 • Orin 138 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Àmì Tó Fi Hàn Pé Jèhófà Máa Mú Ísírẹ́lì Padà Bọ̀ Sípò”: (10 min.)

  • Jer 32:6-9, 15​—Jèhófà sọ fún Jeremáyà pé kó ra pápá kan, èyí tó jẹ́ àmì pé Jèhófà máa mú Ísírẹ́lì padà bọ̀ sípò (it-1 105 ¶2)

  • Jer 32:10-12​—Jeremáyà ṣe gbogbo ohun tí òfin sọ nígbà tó fẹ́ ra pápá náà (w07 3/15 11 ¶3)

  • Jer 33:7, 8​—Jèhófà ṣèlérí pé òun máa ‘wẹ’ àwọn tó wà nígbèkùn “mọ́ gaara” (jr 152 ¶22-23)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Jer 33:15​—Ta ni “èéhù” Dáfídì? (jr 173 ¶10)

  • Jer 33:23, 24​—“Ìdílé méjì” wo ni ẹsẹ yìí mẹ́nu kàn? (w07 3/15 11 ¶4)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 32:1-12

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò tó dá lórí “Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò.” Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì tó wà níbẹ̀. Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n fi fídíò tó nasẹ̀ ìwé pẹlẹbẹ náà Ìdílé Rẹ Lè Jẹ́ Aláyọ̀ han àwọn èèyàn nígbà tí wọ́n bá ń fi ìwé náà lọni.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

 • Orin 6

 • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.) Ẹ tún lè jíròrò ẹ̀kọ́ tá a rí kọ́ nínú Ìwé Ọdọọdún. (yb16 67-71)

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 12 ¶1-8, àpótí “Ó Fi Ìrẹ̀lẹ̀ Gba Ìbáwí

 • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

 • Orin 23 àti Àdúrà