• Orin 99 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Tá A Bá Fẹ́ Wà Ní Àlááfíà Pẹ̀lú Jèhófà, A Ní Láti Bọ̀wọ̀ fún Jésù Ọmọ Rẹ̀”: (10 min.)

  • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù.]

  • Sm 2:1-3—Bíbélì sọ tẹ́lẹ̀ pé àwọn alákòóso máa kórìíra Jèhófà àti Jésù (w04 7/15 ojú ìwé 16 àti 17 ìpínrọ̀ 4 sí 8; it-1-E ojú ìwé 507; it-2-E ojú ìwé 386 ìpínrọ̀ 3)

  • Sm 2:8-12—Awọn tó bá bọ̀wọ̀ fún Ọba tí Jèhófà fòróró yàn nìkan ni yóò ní ìyè (w04 8/1 ojú ìwé 5 ìpínrọ̀ 2 àti 3)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Sm 2:7—Kí ni “àṣẹ àgbékalẹ̀ Jèhófà”? (w06 5/15 ojú ìwé 17 ìpínrọ̀ 6)

  • Sm 3:2—Kí ni ọ̀rọ̀ náà Sélà túmọ̀ sí? (w06 5/15 ojú ìwé 18 ìpínrọ̀ 2)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sáàmù 8:1–9:10

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn wp16.3—Ka ẹsẹ Ìwé Mímọ́ kan fún onílé lórí fóònú tàbí tablet rẹ.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn wp16.3—Kí onílé sọ pé òun ò fẹ́ kó o ka Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, kó o wá ka ìtumọ̀ Bíbélì míì lórí JW Library.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 12 ìpínrọ̀ 12 àti 13—Gba ẹni tí ò ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ níyànjú pé kó fi JW Library sórí fóònú tàbí tablet rẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI