Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 19-25

Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Jẹ́ Ká Mọ Púpọ̀ Sí I Nípa Mèsáyà

Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Jẹ́ Ká Mọ Púpọ̀ Sí I Nípa Mèsáyà

ÌWÉ MÍMỌ́

ÀSỌTẸ́LẸ̀

ÌMÚṢẸ ÀSỌTẸ́LẸ̀

Sáàmù 22:1

Bíi pé Ọlọ́run fi í sílẹ̀

Mátíù 27:46; Máàkù 15:34

Sáàmù 22:7, 8

Wọ́n kẹ́gàn rẹ̀ lórí òpó igi oró

Mátíù 27:39-43

Sáàmù 22:16

Wọ́n kàn-án mọ́gi

Mátíù 27:31; Máàkù 15:25; Jòhánù 20:25

Sáàmù 22:18

Wọ́n ṣẹ́ kèké lé aṣọ rẹ̀

Mátíù 27:35

Sáàmù 22:22

Ó mú ipò iwájú nínú pípolongo orúkọ Jèhófà

Jòhánù 17:6