Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Tọkọtaya kan ń fi tablet wọn kẹ́kọ̀ọ́ pa pọ̀

ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI May 2016

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Ohun tá a lè sọ tá a bá fẹ́ fi ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ àti ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni lọni. Wo àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ yìí, kó o sì kọ ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tìrẹ.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Inú Jèhófà Máa Ń Dùn Tá A Bá Gbàdúrà Fáwọn Ẹlòmí ì

Jèhófà sọ pé kí Jóòbù gbàdúrà fún àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ tí kò fi ìfẹ́ bá a lò. Báwo ni Jèhófà ṣe bù kún Jóòbù torí ìgbàgbọ́ àti ìfaradà rẹ̀? (Jóòbù 38-42)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ǹjẹ́ Ò Ń Lo Ètò Ìṣiṣẹ́ JW Library?

Báwo lo ṣe lè ní JW Library? Báwo ló ṣe lè lò ó ní ìpàdé àti lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Tá A Bá Fẹ́ Wà Ní Àlááfíà Pẹ̀lú Jèhófà, A Ní Láti Bọ̀wọ̀ fún Jésù Ọmọ Rẹ̀

Kí ní ìṣarasíhùwà àwọn orílẹ̀-èdè sí àṣẹ tí Ọlọ́run fún Jésù? Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì pé ká bọ̀wọ̀ fún Jésù, Ọba tí Ọlọ́run fòróró yàn (Sáàmù 2)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ta Ló Lè Jẹ́ Àlejò Nínú Àgọ́ Jèhófà?

Sáàmù 15 sọ ohun tí Jèhófà Ọlọ́run máa ń wò lára ẹnì kan kó tó lè di ọ̀rẹ́ rẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Àwọn Ọ̀nà Tó O Lè Gbà Lo Ètò Ìṣiṣẹ́ JW Library

Bí o ṣe lè lo ètò ìṣiṣẹ́ yìí láti fi ṣe ìdákẹ́kọ̀ọ́, tó o bá wà ní ìpàdé àti lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Jẹ́ Ká Mọ Púpọ̀ Sí I Nípa Mèsáyà

Wo bí àwọn àsọtẹ́lẹ̀ nípa Mèsáyà, tó wà nínú Sáàmù 22 ṣe ṣẹ sí Jésù lára.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Bẹ Jèhófà Pé Kó Jẹ́ Kó O Ní Ìgboyà

Kí ló máa jẹ́ ká ní ìgboyà bíi ti Dáfídì? (Sáàmù 27)