Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

March 5-​11

MÁTÍÙ 20-21

March 5-​11
 • Orin 76 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ẹnì Yòówù Tí Ó Bá Fẹ́ Di Ẹni Ńlá Láàárín Yín Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Òjíṣẹ́ Yín”: (10 min.)

  • Mt 20:3​—Àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn Farisí onígbèéraga fẹ́ràn káwọn èèyàn máa kí wọn “ní ibi ọjà” (“Ibi Ọjà” àwòrán àti fídíò lórí Mt 20:3, nwtsty)

  • Mt 20:​20, 21​—Àwọn àpọ́sítélì méjì béèrè fún ipò ọlá àti ipò àṣẹ (“ìyá àwọn ọmọkùnrin Sébédè,” “ọ̀kan ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ àti ọ̀kan ní òsì rẹ” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 20:20, 21, nwtsty)

  • Mt 20:​25-28​—Jésù sọ pé ó yẹ kí àwọn ọmọ ẹ̀yìn òun jẹ́ òjíṣẹ́ tó nírẹ̀lẹ̀ (“òjíṣẹ́,” “kì í ṣe kí a lè ṣe ìránṣẹ́ fún un, bí kò ṣe kí ó lè ṣe ìránṣẹ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 20:26, 28, nwtsty)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Mt 21:9​—Nígbà táwọn èrò kígbe pé: “Gba Ọmọkùnrin Dáfídì là, ni àwa bẹ̀bẹ̀!” kí ni wọ́n ní lọ́kàn? (“Gbà là, ni àwa bẹ̀bẹ̀,” “Ọmọkùnrin Dáfídì” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 21:9, nwtsty)

  • Mt 21:​18, 19​—Kí nìdí tí Jésù fi sọ fún igi ọ̀pọ̀tọ́ náà pé kó rọ? (jy 244 ¶4-6)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mt 20:​1-19

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

 • Orin 99

 • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)

 • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù March.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv àfikún àlàyé Ìgbà Wo Ló Yẹ Kí Obìnrin Máa Borí, Kí sì Nìdí?

 • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

 • Orin 53 àti Àdúrà