• Orin 143 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ẹ Máa Bá A Nìṣó ní Ṣíṣọ́nà”: (10 min.)

  • Mt 25:​1-6​—Àwọn wúńdíá olóye márùn-ún àtàwọn wúńdíá òmùgọ̀ márùn-ún jáde lọ pàdé ọkọ ìyàwó

  • Mt 25:​7-10​—Àwọn wúńdíá òmùgọ̀ náà kò sí níbẹ̀ nígbà tí ọkọ ìyàwó dé

  • Mt 25:​11, 12​—Àwọn wúńdíá olóye nìkan ló wọlé síbi àsè ìgbéyàwó náà

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Mt 25:​31-33​—Ṣàlàyé àpèjúwe àwọn àgùntàn àtàwọn ewúrẹ́. (w15 3/15 27 ¶7)

  • Mt 25:40​—Ọ̀nà wo la lè gbà fi hàn pé a jẹ́ ọ̀rẹ́ àwọn arákùnrin Kristi? (w09 10/15 16 ¶16-18)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mt 25:​1-23

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Pe ẹni náà wá sí Ìrántí Ikú Kristi.

 • Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó o máa lò, fi ọ̀kan nínú àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ lọ̀ ọ́.

 • Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w15 3/15 27 ¶7-10​—Àkòrí: Báwo Ni Àpèjúwe Àwọn Àgùntàn Àtàwọn Ewúrẹ́ Ṣe Fi Hàn Pé Iṣẹ́ Ìwàásù Ṣe Pàtàkì?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI