Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi (March 3-31): A fẹ́ pè yín sí ìpàdé pàtàkì kan. Ìwé ìkésíni tiyín rèé. Ní ọjọ́ Saturday, March 31, ọ̀pọ̀ èèyàn jákèjádò ayé máa pé jọ láti ṣe ìrántí ikú Jésù Kristi. Wàá rí àkókò àti ibi tá a ti máa ṣe ìpàdé náà nínú ìwé yìí. A tún fẹ́ kó o wá gbọ́ àsọyé kan ní ọ̀sẹ̀ tó ṣáájú ìgbà yẹn, àkòrí rẹ̀ ni “Ta Ni Jésù Kristi Jẹ́ Gan-an?”

Ìbéèrè fún Ìgbà Míì Tí Ẹni Náà Bá Nífẹ̀ẹ́ Sí Ọ̀rọ̀ Rẹ: Kí nìdí tí Jésù fi kú?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Kí nìdí tí Jésù fi kú?

Bíbélì: Mt 20:28

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àǹfààní wo ni ìràpadà ṣe fún wa?

○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Àǹfààní wo ni ìràpadà ṣe fún wa?

Bíbélì: Ro 6:23

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọ rírì ìràpadà?