Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  March 2017

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 1-4

“Mo Wà Pẹ̀lú Rẹ Láti Dá Ọ Nídè”

“Mo Wà Pẹ̀lú Rẹ Láti Dá Ọ Nídè”
WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

Ó ṣeé ṣe kí Jeremáyà ti fẹ́rẹ̀ẹ́ pé ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n [25] nígbà tí Jèhófà yàn án láti di wòlíì. Jeremáyà ronú pé òun ò tóótun láti ṣe iṣẹ́ náà, àmọ́ Jèhófà mú un dá a lójú pé òun máa tì í lẹ́yìn.

  1. 647

    Jeremáyà di wòlíì

  2. 607

    Jerúsálẹ́mù pa run

  3. 580

    Ìwé kíkọ parí

Gbogbo déètì jẹ́ ṣáájú Sànmánì Kristẹni