• Orin 23 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Mo Wà Pẹ̀lú Rẹ Láti Dá Ọ Nídè”: (10 min.)

  • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jeremáyà.]

  • Jer 1:6—Jeremáyà lọ́ tìkọ̀ láti gba iṣẹ́ tuntun tí Ọlọ́run yàn fún un (w11 3/15 29 ¶4)

  • Jer 1:7-10, 17-19—Jèhófà ṣèlérí fún Jeremáyà pé òun máa fún un lókun òun sì máa ràn án lọ́wọ́ (w05 12/15 24 ¶18; jr 88 ¶14-15)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Jer 2:13, 18—Nǹkan burúkú mejì wo làwọn ọmọ Ísírẹ́lì aláìṣòótó ṣe? (w07 3/15 9 ¶8)

  • Jer 4:10—Ọ̀nà wo ni Jèhófà gbà “tan” àwọn èèyàn rẹ̀? (w07 3/15 9 ¶4)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 4:1-10

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò tó dá lórí “Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò.” Jẹ́ kí àwọn ará wo àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI