Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  March 2017

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 8-11

Tá A Bá Tẹ̀lé Ìtọ́sọ́nà Jèhófà Nìkan La Máa Ṣàṣeyọrí

Tá A Bá Tẹ̀lé Ìtọ́sọ́nà Jèhófà Nìkan La Máa Ṣàṣeyọrí

Àwa èèyàn kò lágbára, a ò sì láṣẹ láti darí ara wa

10:21-23

  • Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tú ká, torí pé àwọn aṣáájú wọn kò wádìí ọ̀rọ̀ lọ́dọ̀ Jèhófà

  • Àwọn tó ń tẹ̀lé ìtọ́sọ́nà Jèhófà ń ní àláàfíà, ayọ̀, wọ́n sì máa ń ṣàṣeyọrí