• Orin 66 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Wọn Ò Ṣe Ohun Tí Ọlọ́run Fẹ́ Mọ́”: (10 min.)

  • Jer 6:13-15—Jeremáyà tú àṣírí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (w88 4/1 11-12 ¶7-8)

  • Jer 7:1-7—Jèhófà gbìyànjú láti mú kí wọ́n ronú pìwà dà (w88 4/1 12 ¶9-10)

  • Jer 7:8-15—Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì rò pé Jèhófà kò ní ṣe ohunkóhun (jr 21 ¶12)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Jer 6:16—Kí ni Jèhófà ń rọ àwọn èèyàn rẹ̀ láti ṣe? (w05 11/1 23 ¶11)

  • Jer 6:22, 23—Kí nìdí tá a fi lè sọ pé àwọn èèyàn kan “ń bọ̀ láti ilẹ̀ àríwá”? (w88 4/1 13 ¶15)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 5:26–6:5

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-36—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-36—Jíròrò “Rò Ó Wò Ná.” Pe ẹni náà wá sí Ìrántí Ikú Kristi.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jl ẹ̀kọ́ 1—Pe ẹni náà wá sí Ìrántí Ikú Kristi.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI