Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  March 2016

March 21 sí 27

JÓÒBÙ 6-10

March 21 sí 27
 • Orin 68 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Jóòbù Ọkùnrin Olóòótọ́ Sọ Ẹ̀dùn Ọkàn Rẹ̀”: (10 min.)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Job 6:14—Báwo ni Jóòbù ṣe fi hàn pé ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ ṣe pàtàkì? (w10 11/15 ojú ìwé 32 ìpínrọ̀ 20)

  • Job 7:9, 10; 10:21—Tí Jóòbù bá gbà pé àjíǹde wà, kí nìdí tó fi sọ ọ̀rọ̀ tó wà nínú ẹsẹ yìí? (w06 3/15 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 11)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: Job 9:1-21 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: wp16.2 ojú ìwé 16—Sọ bí a ṣe ń fi ọrẹ ṣètìlẹyìn fún iṣẹ́ wa. (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

 • Ìpadàbẹ̀wò: wp16.2 ojú ìwé 16—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá. (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: fg ẹ̀kọ́ 2 ìpínrọ̀ 6 sí 8 (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

 • Orin 114

 • Máa Lo Ìjìnlẹ̀ Òye Tó O Bá Ń Tu Àwọn Èèyàn Nínú: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tí àwọn alàgbà wò láìpẹ́ yìí ní Ilé Ẹ̀kọ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́. Lẹ́yìn náà, ní kí àwọn ará sọ bí àwọn arákùnrin méjì tá a rí nínú fídíò náà ṣe fi àpẹẹrẹ rere lélẹ̀ fún wa nípa bí a ṣe lè tu ẹni tó sọ ẹ̀dùn ọkàn rẹ̀ fún wa nínú lẹ́yìn tí èèyàn rẹ̀ kan kú.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: ia orí 11 ìpínrọ̀ 12 sí 20, àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 98 (30 min.)

 • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

 • Orin 27 àti Àdúrà