Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

March 14 sí 20

JÓÒBÙ 1-5

March 14 sí 20
 • Orin 89 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Jóòbù Pa Ìwà Títọ́ Rẹ̀ Mọ́ Nígbà Àdánwò”: (10 min.)

  • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jóòbù.]

  • Job 1:8-11—Sátánì jiyàn nípa ìdí tí Jóòbù fi pa ìwà títọ́ rẹ̀ mọ́ (w11 5/15 ojú ìwé 17 ìpínrọ̀ 6 sí 8; w09 4/15 ojú ìwé 3 ìpínrọ̀ 3 àti 4)

  • Job 2:2-5—Sátánì sọ pé gbogbo èèyàn ò ní lè pa ìwà títọ́ wọn mọ́ (w09 4/15 ojú ìwé 4 ìpínrọ̀ 6)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Job 1:6; 2:1—Àwọn wo ni Jèhófà gbà láyè kó wọlé wá láti dúró níwájú rẹ̀? (w06 3/15 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 6)

  • Job 4:7, 18, 19—Ọ̀rọ̀ tí kì í ṣe òótọ́ wo ni Élífásì sọ fún Jóòbù? (w14 3/15 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 3; w05 9/15 ojú ìwé 26 ìpínrọ̀ 4-5; w95 2/15 ojú ìwé 27 ìpínrọ̀ 5-6)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: Job 4:1-21 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

 • Orin 88

 • Má Ṣe Jẹ́ Kí Àwọn Ẹgbẹ́ Ẹ Ba Ìwà Ẹ Jẹ́!: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Má Ṣe Jẹ́ Kí Àwọn Ẹgbẹ́ Ẹ Ba Ìwà Ẹ Jẹ́! ó wà lórí ìkànnì jw.org/yo (Lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́.) Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará láwọn ìbéèrè yìí: Àwọn nǹkan wo làwọn ọmọ kan ń ṣe nílé ẹ̀kọ́ tí wọ́n á sì fẹ́ káwọn ọmọ míì máa bá wọn ṣe? Báwo làwọn ọmọ ṣe lè tẹ̀ lé ìlànà tó wà ní Ẹ́kísódù 23:2? Àwọn ohun mẹ́rin wo làwọn ọmọdé lè ṣe táá jẹ́ kí wọ́n lè hùwà ọgbọ́n tí wọ́n á sì pa ìwà títọ́ wọn mọ́? Ní kí àwọn ọ̀dọ́ sọ ìrírí tó gbádùn mọ́ni tí wọ́n ní.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: ia orí 11 ìpínrọ̀ 1 sí 11 (30 min.)

 • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

 • Orin 149 àti Àdúrà