• Orin 37 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Kọ Ìdẹwò Bí I Ti Jésù”: (10 min.)

  • Lk 4:1-4​—Jésù kò gba ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ti ara láyè (w13 8/15 25 ¶8)

  • Lk 4:5-8​—Ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ojú kò gba Jésù lọ́kàn (w13 8/15 25 ¶10)

  • Lk 4:9-12​—Jésù kò tiẹ̀ gbìyànjú láti ṣe àṣehàn [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Odi Orí Òrùlé Tẹ́ńpìlì.] (“Odi Orí Òrùlé Tẹ́ńpìlì” fídíò àti àwòrán lórí Lk 4:9-12, nwtsty; w13 8/15 26 ¶12)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Lk 4:17​—Kí ló fi hàn pé Jésù mọ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run dáadáa? (“àkájọ ìwé wòlíì Aísáyà” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 4:17, nwtsty)

  • Lk 4:25​—Báwo ni ọ̀dá tó wáyé nígbà ayé Èlíjà ṣe gùn tó? (“fún ọdún mẹ́ta àti oṣù mẹ́fà” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 4:25, nwtsty)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lk 4:​31-44

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Kó o wá fún un ní káàdì ìkànnì JW.ORG.

 • Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó o máa lò, fi ọ̀kan nínú àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ lọ̀ ọ́.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jl ẹ̀kọ́ 28

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI