• Orin 133 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ṣé Àjọṣe Yín Pẹ̀lú Jèhófà Túbọ̀ Ń Lágbára Sí I?”: (10 min.)

  • Lk 2:41, 42​—Jésù àti àwọn òbí rẹ̀ jọ máa ń lọ sí àjọyọ̀ Ìrékọjá ọdọọdún (“ó jẹ́ àṣà àwọn òbí rẹ̀” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 2:41, 42, nwtsty)

  • Lk 2:46, 47​—Jésù tẹ́tí sí àwọn aṣáájú ẹ̀sìn, ó sì bi wọ́n ní ìbéèrè (“ó sì ń bi wọ́n ní ìbéèrè,” “wọ́n ń ṣe kàyéfì léraléra” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 2:46, 47, nwtsty)

  • Lk 2:51, 52​—Jésù “ń bá a lọ ní fífi ara rẹ̀ sábẹ́” àwọn òbí rẹ̀, ó sì rí ojú rere Ọlọ́run àti èèyàn (“bá a lọ ní fífi ara rẹ̀ sábẹ́ wọn” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 2:51, 52, nwtsty)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Lk 2:14​—Kí ni ìtumọ̀ Lúùkù 2:14? (“àti lórí ilẹ̀ ayé àlàáfíà láàárín àwọn ẹni ìtẹ́wọ́gbà,” “àwọn ẹni ìtẹ́wọ́gbà” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 2:14, nwtsty)

  • Lk 3:23​—Ta ni bàbá Jósẹ́fù? (wp16.3 9 ¶1-3)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lk 2:1-20

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, dáhùn ìbéèrè kan táwọn èèyàn sábà máa ń béèrè ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù.

 • Ìpadàbẹ̀wò Kejì​—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

 • Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w14 2/15 26-27​—Àkòrí: Kí Ló Mú Kí Àwọn Júù Ọ̀rúndún Kìíní Máa “Fojú Sọ́nà” fún Mèsáyà?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI