●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Báwo la ṣe lè mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú?

Bíbélì: Ais 46:10

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì wo là ń rí tó ń ṣẹ lónìí?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì wo là ń rí tó ń ṣẹ lónìí?

Bíbélì: Mt 24:​6, 7, 14

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló máa ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn tí “òpin” bá ti dé?

○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Kí ló máa ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn tí “òpin” bá ti dé?

Bíbélì: Iṣi 21:4

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ibo ni àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì yìí ti máa ṣẹ?