• Orin 141 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ṣé O Máa Wà Lára Àwọn Tá A Máa Sàmì Sí Láti Là Á Já?”: (10 min.)

  • Isk 9:​1, 2​—Ìran tí Ìsíkíẹ́lì rí kọ́ wa ní ẹ̀kọ́ pàtàkì (w16.06 16-17)

  • Isk 9:​3, 4​—Tó bá di àkókò kan nígbà tí ìpọ́njú ńlá bá ń lọ lọ́wọ́, Jésù máa sàmì sí àwọn tó bá fetí sí ìhìn rere láti là á já

  • Isk 9:​5-7​—Jèhófà máa pa àwọn ẹni burúkú run, ṣùgbọ́n ó máa dá àwọn olódodo sí

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Isk 7:19​—Báwo ni ẹsẹ yìí ṣe lè mú ká gbáradì fún ohun tó ń bọ̀ wá ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú? (w09 9/15 23 ¶10)

  • Isk 8:12​—Báwo ni ẹsẹ yìí ṣe fi hàn pé àìnígbàgbọ́ lè mú kéèyàn bẹ̀rẹ̀ sí í hùwà tí kò dáa? (w11 4/15 26 ¶14)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 8:​1-12

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣi 4:11​—⁠Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 11:5; 2Kọ 7:1​—⁠Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 127 ¶4-5​—⁠Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI