Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  June 2017

June 19-​25

ÌSÍKÍẸ́LÌ 1-5

June 19-​25
 • Orin 75 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Inú Ìsíkíẹ́lì Dùn Láti Kéde Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run”: (10 min.)

  • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìsíkíẹ́lì.]

  • Isk 2:9–3:2​—Ìsíkíẹ́lì jẹ àkájọ ìwé “orin arò àti ìkédàárò àti ìpohùnréré ẹkún” (w08 7/15 8 ¶6-7; it-1 1214)

  • Isk 3:3​—Ìsíkíẹ́lì mọyì bí Jèhófà ṣe yan òun láti jẹ́ wòlíì (w07 7/1 12 ¶3)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Isk 1:​20, 21, 26-28​—Kí ni kẹ̀kẹ́ ẹṣin òkè ọ̀run ṣàpẹẹrẹ? (w07 7/1 11 ¶6)

  • Isk 4:​1-7​—Ṣé lóòótọ́ ni Ìsíkíẹ́lì ṣe àṣefihàn bí àwọn ọ̀tá ṣe máa sàga ti Jerúsálẹ́mù? (w07 7/1 12 ¶4)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 1:​1-14

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-32​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-32​—Jẹ́ kí onílé wo fídíò náà, Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìdílé Rẹ Lè Jẹ́ Aláyọ̀, kó o sì fún un ní ìwé pẹlẹbẹ náà.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 143 ¶20-21​—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI