• Orin 95 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà, Kí O sì Máa Ṣe Rere”: (10 min.)

  • Sm 37:1, 2—Pọkàn pọ̀ sórí bó o ṣe ń sin Jèhófà, má ṣe wo àṣeyọrí àwọn aṣebi tí kì í tọ́jọ́ (w03 12/1 ojú ìwé 9 àti 10 ìpínrọ̀ 3 sí 6)

  • Sm 37:3-6—Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, máa ṣe rere, kó o sì gba ìbùkún (w03 12/1 ojú ìwé 10 sí 12 ìpínrọ̀ 7 sí 15)

  • Sm 37:7-11—Fi sùúrù dúró de Jèhófà láti mú àwọn ẹni burúkú kúrò (w03 12/1 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 16 sí 20)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Sm 34:18—Báwo ni Jèhófà ṣe máa ń bójú tó àwọn “oníròbìnújẹ́ ní ọkàn-àyà” àti “àwọn tí a wó ẹ̀mí wọn palẹ̀”? (w11 6/1 ojú ìwé 19)

  • Sm 34:20—Báwo ni àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣe ṣẹ sí Jésù lára? (w13 12/15 ojú ìwé 21 ìpínrọ̀ 19)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 35:19–36:12

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kó o sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n kọ àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ wọn sílẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI