Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  June 2016

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 38-44

Jèhófà Máa Ń Gbé Àwọn Aláìsàn Ró

Jèhófà Máa Ń Gbé Àwọn Aláìsàn Ró

Àwọn olóòótọ́ ìránṣẹ́ Ọlọ́run gbà pé Jèhófà máa ran àwọn lọ́wọ́ nígbà ìṣòro

41:1-4

  • Dáfídì ṣàìsàn gan-an

  • Dáfídì gba ti àwọn ẹni rírẹlẹ̀ rò

  • Dáfídì kò retí pé kí Jèhófà wo òun sàn lọ́nà ìyanu, àmọ́ ó bẹ Jèhófà pé kó tu òun nínú, kó fún òun lọ́gbọ́n, kó sì ran òun lọ́wọ́

  • Jèhófà ka Dáfídì sí ọkùnrin oníwà títọ́