Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  June 2016

June 13 sí 19

SÁÀMÙ 38-44

June 13 sí 19
 • Orin 4 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Jèhófà Máa Ń Gbé Àwọn Aláìsàn Ró”: (10 min.)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Sm 39:1, 2—Kí nìdí tó fi yẹ ká kíyè sí ohun tá a máa sọ? (w09 5/15 ojú ìwé 4 ìpínrọ̀ 5; w06 5/15 ojú ìwé 20 ìpínrọ̀ 12)

  • Sm 41:9—Báwo ni Jésù ṣe jẹ́ ká mọ̀ pé irú ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Dáfídì ló ṣẹlẹ̀ sí òun náà? (w11 8/15 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 5; w08 9/15 ojú ìwé 5 ìpínrọ̀ 11)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 42:6–43:5

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g16.3

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Àpilẹ̀kọ tó dá lórí kókó iwájú ìwé ìròyìn g16.3

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 2 ìpínrọ̀ 4 àti 5—Ní ìparí ìkẹ́kọ̀ọ́, jẹ́ kí akẹ́kọ̀ọ́ rẹ wo fídíò tó wà lórí ìkànnì jw.org/yo tá a pè ní Ṣé Ọlọ́run ní Orúkọ?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI