Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Àwọn akéde ń fi ìwé àṣàrò kúkúrú lọni nílùú Málítà

ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI June 2016

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Ohun tá a lè sọ tá a bá fẹ́ fi ìwé ìròyìn Jí! àti àwọn ìwé àṣàrò kúkúrú lọni. Wo àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ yìí, kó o sì kọ ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tìrẹ.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà, Kí O sì Máa Ṣe Rere

Máa fi ìmọ̀ràn tó wúlò tó wà ní Sáàmù 37 sílò.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Bí O Ṣe Lè Fi Fídíò Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́

Kí nìdí tó fi yẹ ká máa lo àwọn fídíò yìí lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù? Báwo ni àwọn fídíò yìí ṣe lè mú kí ìkọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ wa sunwọ̀n sí i?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Máa Ń Gbé Àwọn Aláìsàn Ró

Ọ̀rọ̀ tí Ọlọ́run mí sí tí Dáfídì sọ tó wà ní Sáàmù 41 máa fún àwọn olóòótọ́ ìránṣẹ́ Jèhófà lóde òní lókun láti fara da àìsàn tàbí ìṣòro.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Kò Ní Fi Ẹni Tó Ní Ìròbìnújẹ́ Ọkàn Sílẹ̀

Ní Sáàmù 51, Dáfídì sọ àkóbá tí ẹ̀ṣẹ̀ tó lágbára tó dá ṣe fún un. Kí ló ràn án lọ́wọ́ láti lè ronú pìwà dà?

ÌGBÉ AYÉ KRISTẸNI

Ọgọ́rùn-ún Ọdún Ti Kọjá, Ìjọba Ọlọ́run Ṣì Ń Ṣàkóso!

Lo àwọn ìbéèrè náà láti fi jíròrò àwọn ohun tí Ìjọba Ọlọ́run ti gbéṣe láti ọdún 1914.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Ju Ẹrù Ìnira Rẹ Sọ́dọ̀ Jèhófà”

Ọ̀rọ̀ Dáfídì tí Ọlọ́run mí sí tó wà ní Sáàmù 55:22 lè mú ká fara da ìṣòro, àníyàn tàbí ìdààmú ọkàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

“Ọlọ́run Ni Olùrànlọ́wọ́ Mi”

Dáfídì yin Jèhófà nítorí ọ̀rọ̀ Rẹ̀. Ẹsẹ Bíbélì wo ló ti ràn ẹ́ lọ́wọ́ nígbà tó o wà nínú ìṣòro?