Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  July 2017

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 11-14

Ṣé O Máa Ń Jẹ́ Kí Jèhófà Tọ́ Ẹ Sọ́nà?

Ṣé O Máa Ń Jẹ́ Kí Jèhófà Tọ́ Ẹ Sọ́nà?

Ìtọ́ni wo ni Jèhófà fún wa?

11:19

  • Eré ìnàjú

  • Aṣọ àti Ìmúra

  • Ìfẹ́ àti Ìdáríjì

Báwo ni mo ṣe lè túbọ̀ máa tẹ̀ lé àwọn ìtọ́ni Jèhófà?

11:20

  • Eré ìnàjú

  • Aṣọ àti Ìmúra

  • Ìfẹ́ àti Ìdáríjì