• Orin 52 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ṣé O Máa Ń Jẹ́ Kí Jèhófà Tọ́ Ẹ Sọ́nà?”: (10 min.)

  • Isk 11:​17, 18​—Jèhófà ṣèlérí pé òun máa mú ìjọsìn tòótọ́ pa dà bọ̀ sípò (w07 7/1 11 ¶4)

  • Isk 11:19​—Jèhófà lè jẹ́ ká túbọ̀ máa fòye mọ àwọn ohun tó fẹ́ ká ṣe (w16.05 15 ¶9)

  • Isk 11:20​—Jèhófà fẹ́ ká máa fi ohun tí à ń kọ́ sílò

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Isk 12:​26-28​—Kí ni àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí sọ pé àwa ìránṣẹ́ Jèhófà ní láti ṣe? (w07 7/1 13 ¶8)

  • Isk 14:​13, 14​—Kí la rí kọ́ nínú bá a ṣe dárúkọ àwọn tó wà nínú ẹsẹ Bíbélì yìí? (w16.05 26 ¶13; w07 7/1 13 ¶9)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 12:​1-10

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò tó dá lórí “Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò.” Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI