Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

July 24-​30

Ìsíkíẹ́lì 21-23

July 24-​30
 • Orin 99 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ẹni Tó Lẹ́tọ̀ọ́ Lábẹ́ Òfin Ni Ọba Tọ́ Sí”: (10 min.)

  • Isk 21:25​—Ọba Sedekáyà ni “ìjòyè burúkú ti Ísírẹ́lì” (w07 7/1 13 ¶11)

  • Isk 21:26​—Ìṣàkóso àwọn ọba tó ń jẹ ní ìlà ìdílé Dáfídì ní Jerúsálẹ́mù máa dópin (w11 8/15 9 ¶6)

  • Isk 21:27​—Jésù Kristi ni “ẹni tí ó ní ẹ̀tọ́ lọ́nà òfin” (w14 10/15 10 ¶14)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Isk 21:3​—Kí ni “idà” tí Jèhófà mú jáde kúrò nínú àkọ̀ rẹ̀? (w07 7/1 14 ¶1)

  • Isk 23:49​—Àṣìṣe wo ni orí ìkẹtàlélógún sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀, kí la sì rí kọ́? (w07 7/1 14 ¶6)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 21:​1-13

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

 • Orin 93

 • Máa Hùwà Tó Bójú Mu Lóde Ẹ̀rí”: (15 min.) Ìjíròrò. Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó bójú tó apá yìí. Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ wo fídíò tó sọ̀rọ̀ nípa bá a ṣe lè máa hùwà tó bójú mu lóde ẹ̀rí.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 15 ¶18-28

 • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

 • Orin 29 àti Àdúrà