Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  July 2017

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 18-20

Tí Jèhófà Bá Ti Dárí Ẹ̀ṣẹ̀ Jini, Ṣé Ó Máa Ń Gbàgbé Rẹ̀?

Tí Jèhófà Bá Ti Dárí Ẹ̀ṣẹ̀ Jini, Ṣé Ó Máa Ń Gbàgbé Rẹ̀?

18:21, 22

  • Bí Jèhófà bá ti dárí ẹ̀ṣẹ̀ ji ẹnì kan, kò ní fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ náà jẹ ẹ́ lọ́jọ́ iwájú.

Àwọn àpẹẹrẹ inú Bíbélì yìí fi wá lọ́kàn balẹ̀ pé Jèhófà ń dárí jini.

Ọba Dáfídì

  • Ẹ̀ṣẹ̀ wo ló dá?

  • Kí nìdí tí Jèhófà fi dárí jì í?

  • Báwo ni Jèhófà ṣe fi hàn pé òun ti dárí jì í?

Ọba Mánásè

  • Ẹ̀ṣẹ̀ wo ló dá?

  • Kí nìdí tí Jèhófà fi dárí jì í?

  • Báwo ni Jèhófà ṣe fi hàn pé òun ti dárí jì í?

Àpọ́sítélì Pétérù

  • Ẹ̀ṣẹ̀ wo ló dá?

  • Kí nìdí tí Jèhófà fi dárí jì í?

  • Báwo ni Jèhófà ṣe fi hàn pé òun ti dárí jì í?

Báwo ni mo ṣe lè máa dárí jini bíi ti Jèhófà?